Font Size
Ìṣe àwọn Aposteli 3:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 3:22
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
22 (A)Mose wí pé, ‘Olúwa Ọlọ́run yín yóò gbé wòlíì kan dìde fún yín nínú àwọn arákùnrin yín, bí èmi; òun ni ẹ̀yin yóò máa gbọ́ tirẹ̀ ní ohun gbogbo tí yóò máa sọ fún un yín.
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 3:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 3:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Yóò sì ṣe, olúkúlùkù ọkàn ti kò bá gbọ́ ti wòlíì náà, òun ni a ó parun pátápátá kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.’
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 7:37
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 7:37
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
37 (A)“Èyí ni Mose náà ti ó wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Ọlọ́run yóò gbé wòlíì kan bí èmi dìde nínú àwọn ènìyàn yín.’
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.