Add parallel Print Page Options

(A)Ó wù mí kí olúkúlùkù dàbí èmi, ṣùgbọ́n gbogbo ènìyàn kò le jẹ́ bákan náà, Ọlọ́run fún olúkúlùkù ènìyàn ní ẹ̀bùn tirẹ̀, ọ̀kan bí irú èyí àti èkejì bí irú òmíràn.

Nítorí náà, mo wí fún àwọn àpọ́n àti opó pé, ó sàn kí wọ́n kúkú wà gẹ́gẹ́ bí èmi tí wà. (B)Ṣùgbọ́n bí wọ́n kò bá lè mú ara dúró, kí wọ́n gbéyàwó tàbí kí wọ́n fẹ́ ọkọ, nítorí pé ó sàn láti gbéyàwó jù láti ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ lọ.

Read full chapter

I wish that all of you were as I am.(A) But each of you has your own gift from God; one has this gift, another has that.(B)

Now to the unmarried[a] and the widows I say: It is good for them to stay unmarried, as I do.(C) But if they cannot control themselves, they should marry,(D) for it is better to marry than to burn with passion.

Read full chapter

Footnotes

  1. 1 Corinthians 7:8 Or widowers