Add parallel Print Page Options

28 (A)Bí ó bá ṣẹlẹ̀ pé ọkùnrin pàdé wúńdíá tí kò ì tí ì ní àfẹ́sọ́nà tí ó sì fi tipátipá bá a ṣe tí a gbá wọn mú.

Read full chapter

28 If a man happens to meet a virgin who is not pledged to be married and rapes her and they are discovered,(A)

Read full chapter

29 Ó ní láti san àádọ́ta fàdákà fún baba obìnrin náà, nítorí tí ó ti bà á jẹ́. Kò lè kọ̀ ọ́ sílẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó sì wà láààyè.

Read full chapter

29 he shall pay her father fifty shekels[a] of silver. He must marry the young woman, for he has violated her. He can never divorce her as long as he lives.

Read full chapter

Footnotes

  1. Deuteronomy 22:29 That is, about 1 1/4 pounds or about 575 grams