Add parallel Print Page Options

43 (A)Ẹ yọ̀ ẹ̀yin orílẹ̀-èdè, pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀
    nítorí òun yóò gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀;
yóò sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá a rẹ̀
    yóò sì ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àti ènìyàn rẹ̀.

Read full chapter