Add parallel Print Page Options

(A)“Ìwọ kò gbọdọ̀ ní ọlọ́run mìíràn pẹ̀lú mi.

Read full chapter

(A)Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ère fún ara yín, tàbí àwòrán ohun kan tí ń bẹ ní òkè ọ̀run, tàbí ti ohun kan tí ń bẹ ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀, tàbí ti ohun kan tí ń bẹ nínú omi ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀.

Read full chapter

17 (A)“Ìwọ kò gbọdọ̀ dá ère òrìṣàkórìṣà fún ara rẹ.

Read full chapter

15 (A)“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó fín ère tàbí gbẹ́ òrìṣà ohun tí ó jẹ́ ìríra níwájú Olúwa, iṣẹ́ ọwọ́ oníṣọ̀nà tí ó gbé kalẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀.”

Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Read full chapter