Add parallel Print Page Options

38 (A)“Èyí ni ìwọ yóò máa fi rú ẹbọ ní orí pẹpẹ náà: Ọ̀dọ́-Àgùntàn méjì ọlọ́dún kan ni ojoojúmọ́ láéláé. 39 Ọ̀dọ́-Àgùntàn kan ni ìwọ yóò fi rú ẹbọ ní òwúrọ̀ àti ọ̀dọ́-àgùntàn èkejì ní àṣálẹ́. 40 Pẹ̀lú ọ̀dọ́-àgùntàn ti àkọ́kọ́ rú ẹbọ ìdámẹ́wàá òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun dídára tí a fi ìdámẹ́rin hínì òróró lára olifi tí a gún, àti ìdámẹ́rin hínì wáìnì bí ẹbọ mímu. 41 Ọ̀dọ́-Àgùntàn kejì ni kí ìwọ kí ó pa rú ẹbọ ní àṣálẹ́ ìwọ yóò sì ṣe sí í gẹ́gẹ́ bí ẹbọ jíjẹ àti ẹbọ mímu bí ti òwúrọ̀ fún òórùn dídùn, ẹbọ tí a fi iná ṣe ni sí Olúwa.

42 “Fún ìrandíran tó ń bọ̀, ni ẹ ó máa ṣe ẹbọ sísun nígbà gbogbo ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ àjọ níwájú Olúwa. Níbẹ̀ èmi yóò pàdé yín, èmi yóò sì bá a yín sọ̀rọ̀;

Read full chapter

38 “This is what you are to offer on the altar regularly each day:(A) two lambs a year old. 39 Offer one in the morning and the other at twilight.(B) 40 With the first lamb offer a tenth of an ephah[a] of the finest flour mixed with a quarter of a hin[b] of oil(C) from pressed olives, and a quarter of a hin of wine as a drink offering.(D) 41 Sacrifice the other lamb at twilight(E) with the same grain offering(F) and its drink offering as in the morning—a pleasing aroma, a food offering presented to the Lord.

42 “For the generations to come(G) this burnt offering is to be made regularly(H) at the entrance to the tent of meeting,(I) before the Lord. There I will meet you and speak to you;(J)

Read full chapter

Footnotes

  1. Exodus 29:40 That is, probably about 3 1/2 pounds or about 1.6 kilograms
  2. Exodus 29:40 That is, probably about 1 quart or about 1 liter