Add parallel Print Page Options

(A)Abramu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.

Read full chapter

Ìbùkún yìí ha jẹ́ ti àwọn akọlà nìkan, tàbí ti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú? Nítorí tí a wí pé, Abrahamu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.

Read full chapter

22 (A)Nítorí náà ni a sì ṣe kà á sí òdodo fún un.

Read full chapter

(A)Gẹ́gẹ́ bí Abrahamu “Ó gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un.”

Read full chapter

23 (A)Ìwé Mímọ́ sì ṣẹ́ tí ó wí pé, “Abrahamu gba Ọlọ́run gbọ́, a sì kà á sí òdodo fún un,” a sì pè é ní ọ̀rẹ́ Ọlọ́run.

Read full chapter