Add parallel Print Page Options

“Ní ti èmi, májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ nìyí. Ìwọ yóò di baba orílẹ̀-èdè púpọ̀. (A)A kì yóò pe orúkọ rẹ̀ ní Abramu mọ́, bí kò ṣe Abrahamu, nítorí, mo ti sọ ọ́ di baba orílẹ̀-èdè púpọ̀. Èmi yóò mú ọ bí si lọ́pọ̀lọpọ̀, ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè ni èmi yóò sì mú ti ara rẹ jáde wá, àwọn ọba pẹ̀lú yóò sì ti inú rẹ jáde. (B)Èmi yóò sì gbé májẹ̀mú mi kalẹ̀ láàrín tèmi tìrẹ, ní májẹ̀mú ayérayé àti láàrín irú-ọmọ rẹ ní ìran-ìran wọn, láti máa ṣe Ọlọ́run rẹ àti ti irú-ọmọ rẹ lẹ́yìn rẹ. (C)Gbogbo ilẹ̀ Kenaani níbi tí ìwọ ti ṣe àjèjì ni èmi yóò fi fún ọ àti fún irú-ọmọ rẹ lẹ́yìn rẹ láéláé, Èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.”

Read full chapter

“As for me, this is my covenant with you:(A) You will be the father of many nations.(B) No longer will you be called Abram[a]; your name will be Abraham,[b](C) for I have made you a father of many nations.(D) I will make you very fruitful;(E) I will make nations of you, and kings will come from you.(F) I will establish my covenant(G) as an everlasting covenant(H) between me and you and your descendants after you for the generations to come, to be your God(I) and the God of your descendants after you.(J) The whole land of Canaan,(K) where you now reside as a foreigner,(L) I will give as an everlasting possession to you and your descendants after you;(M) and I will be their God.(N)

Read full chapter

Footnotes

  1. Genesis 17:5 Abram means exalted father.
  2. Genesis 17:5 Abraham probably means father of many.