Add parallel Print Page Options

21 Ègbé ni fún àwọn tí ó gbọ́n lójú ara wọn
    tí wọ́n jáfáfá lójú ara wọn.

Read full chapter

(A)Bí ẹnikẹ́ni bá ró pé òun mọ ohun kan, kò tí ì mọ̀ bí ó ti yẹ kí ó mọ̀.

Read full chapter

Nítorí bí ènìyàn kan bá ń ro ara rẹ̀ sí ẹnìkan, nígbà tí kò jẹ́ nǹkan, ó ń tan ara rẹ̀ jẹ.

Read full chapter