Add parallel Print Page Options

15 (A)Bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe bomirin àwọn orílẹ̀-èdè ká,
    àwọn ọba yóò sì pa ẹnu wọn mọ́ nítorí rẹ̀.
Nítorí ohun tí a kò sọ fún wọn, wọn yóò rí i,
    àti ohun tí wọn kò tí ì gbọ́, ni yóò sì yé wọn.

Read full chapter