Add parallel Print Page Options

12 (A)Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńlá
    òun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára,
nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ fún ikú,
    tí a sì kà á mọ́ àwọn alárékọjá.
Nítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀,
    ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárékọjá.

Read full chapter

(A)Ṣùgbọ́n a sá a lọ́gbẹ́ nítorí àìṣedéédéé wa
    a pa á lára nítorí àìṣòdodo wa;
ìjìyà tí ó mú àlàáfíà wá fún wa wà lórí i rẹ̀,
    àti nípa ọgbẹ́ rẹ̀ ni a fi mú wa láradá.
Gbogbo wa bí àgùntàn, ti ṣìnà lọ,
    ẹnìkọ̀ọ̀kan wa ti yà sí ọ̀nà ara rẹ̀;
Olúwa sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀
    gbogbo àìṣedéédéé wa.

Read full chapter