Add parallel Print Page Options

(A)Gbọ́ rògbòdìyàn láti ìlú wá,
    gbọ́ ariwo náà láti tẹmpili wá!
Ariwo tí Olúwa ní í ṣe
    tí ó ń san án fún àwọn ọ̀tá rẹ̀ ohun
    tí ó tọ́ sí wọn.

Read full chapter