Add parallel Print Page Options

Ìpín ti ẹ̀yà Simeoni

19 Kèké kejì jáde fún ẹ̀yà Simeoni, ní agbo ilé, ní agbo ilé. Ìní wọn sì wà ní àárín ilẹ̀ Juda. Lára ìpín wọn ní:

Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada, Hasari-Ṣuali, Bala, Esemu, Eltoladi, Betuli, Horma, Siklagi, Beti-Markaboti, Hasari Susa, Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn.

Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani: Ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn: Àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù).

Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé. A mú ogún ìní àwọn ọmọ Simeoni láti ìpín Juda, nítorí ìpín Juda pọ̀ ju èyí tí wọ́n nílò lọ. Báyìí ni àwọn ọmọ Simeoni gba ìní wọn ní àárín ilẹ̀ Juda.

Ìpín fún ẹ̀yà Sebuluni

10 Kèké kẹta jáde fún Sebuluni, ní agbo ilé ní agbo ilé:

Ààlà ìní wọn sì lọ títí dé Saridi. 11 Ó sì lọ sí ìwọ̀-oòrùn ní Marala, ó sì dé Dabbeṣeti, ó sì lọ títí dé odo ní ẹ̀bá Jokneamu. 12 Ó sì yípadà sí ìlà-oòrùn láti Saridi sí ìhà ìlà-oòrùn dé ilẹ̀ Kisiloti-Tabori, ó sì lọ sí Daberati, ó sì gòkè lọ sí Jafia. 13 Nígbà náà ní o lọ sí ìhà ìlà-oòrùn lọ sí Gati-Heferi àti Eti-Kaṣini, ó sì jáde ní Rimoni, ó sì yí sí ìhà Nea. 14 Ní ibẹ̀, ààlà sì yíká ní ìhà àríwá lọ sí Hnatoni ó sì pín ní Àfonífojì Ifita-Eli.

15 Lára wọn ni Katati, Nahalali, Ṣimroni, Idala àti Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn.

16 Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní Sebuluni, ní agbo ilé agbo ilé.

Ìpín fún ẹ̀yà Isakari

17 Kèké kẹrin jáde fún Isakari, agbo ilé ní agbo ilé. 18 Lára ilẹ̀ wọn ni èyí:

Jesreeli, Kesuloti, Ṣunemu, 19 Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati, 20 Rabiti, Kiṣioni, Ebesi, 21 Remeti, Eni-Gannimu, Eni-Hada àti Beti-Pasesi.

22 Ààlà náà sì dé Tabori, Ṣahasuma, àti Beti-Ṣemeṣi, ó sì pin ní Jordani.

Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rìn-dínlógún àti ìletò wọn.

23 Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní ẹ̀yà Isakari, ní agbo ilé agbo ilé.

Ìpín fún ẹ̀yà Aṣeri

24 Kèké karùn-ún jáde fún ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé. 25 Lára ilẹ̀ wọn ni èyí:

Helikati, Hali, Beteni, Akṣafu, 26 Allameleki, Amadi, àti Miṣali. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ààlà náà dé Karmeli àti Ṣihori-Libinati. 27 Nígbà náà ni o yí sí ìhà ìlà-oòrùn Beti-Dagoni, dé Sebuluni àti Àfonífojì Ifita-Eli, ó sì lọ sí àríwá sí Beti-Emeki àti Neieli, ó sì kọjá lọ sí Kabuli ní apá òsì. 28 Ó sì lọ sí Abdoni, Rehobu, Hammoni àti Kana títí dé Sidoni ńlá. 29 Ààlà náà sì tẹ̀ sí ìhà Rama, ó sì lọ sí ìlú olódi Tire, ó sì yà sí Hosa, ó sì jáde ní Òkun ní ilẹ̀ Aksibu, 30 Uma, Afeki àti Rehobu.

Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn.

31 Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé.

Ìpín fún ẹ̀yà Naftali

32 Ìpín kẹfà jáde fún Naftali, agbo ilé ní agbo ilé:

33 Ààlà wọn lọ láti Helefi àti igi ńlá ní Saananimu nímù; kọjá lọ sí Adami Nekebu àti Jabneeli dé Lakkumu, ó sì pín ní Jordani. 34 Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí Asnoti-Tabori ó sì jáde ní Hukoki. Ó sì dé Sebuluni, ní ìhà gúúsù Aṣeri ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Juda ní Jordani ní ìhà ìlà-oòrùn.

35 Àwọn ìlú olódi sì Siddimu, Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti, 36 Adama, Rama Hasori, 37 Kedeṣi, Edrei, Eni-Aṣọri, 38 Ironi, Migdali-Eli, Horemu, Beti-Anati àti Beti-Ṣemeṣi.

Wọ́n sì jẹ́ ìlú mọ́kàn-dínlógún àti ìletò wọn.

39 Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Naftali, ní agbo ilé sí agbo ilé.

Ìpín fún ẹ̀yà Dani

40 Ìbò kéje jáde fún ẹ̀yà Dani, ní agbo ilé ní agbo ilé. 41 Ilẹ̀ ìní wọn nìwọ̀nyí:

Sora, Eṣtaoli, Iri-Ṣemesi, 42 Ṣaalabini, Aijaloni, Itila, 43 Eloni, Timna, Ekroni, 44 Elteke, Gibetoni, Baalati, 45 Jehudu, Bene-Beraki, Gati-Rimoni, 46 Me Jakoni àti Rakkoni, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó kọjú sí Joppa.

47 (Ṣùgbọ́n àwọn ará Dani ní ìṣòro láti gba ilẹ̀ ìní wọn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì kọlu Leṣemu, wọ́n sì gbà á, wọ́n sì fi idà kọlù ú, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀. Wọ́n sì ń gbé ní Leṣemu, wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Dani orúkọ baba ńlá wọn).

48 Àwọn ìlú wọ́n yí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Dani, ní agbo ilé agbo ilé.

Ìpín fún ẹ̀yà Joṣua

49 Nígbà tí wọ́n ti parí pínpín ilẹ̀ náà ní ìpín ti olúkúlùkù, àwọn ará Israẹli fún Joṣua ọmọ Nuni ní ìní ní àárín wọn 50 Olúwa ti pàṣẹ, wọ́n fún un ni ìlú tí ó béèrè fún—Timnati Serah ní ìlú òkè Efraimu. Ó sì kọ́ ìlú náà, ó sì ń gbé ibẹ̀.

51 Wọ̀nyí ni àwọn ilẹ̀ tí Eleasari àlùfáà, Joṣua ọmọ Nuni àti àwọn olórí ẹ̀yà agbo ilé Israẹli fi ìbò pín ní Ṣilo ní iwájú Olúwa ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. Báyìí ni wọ́n parí pínpín ilẹ̀ náà.

Allotment for Simeon(A)

19 The second lot came out for the tribe of Simeon according to its clans. Their inheritance lay within the territory of Judah.(B) It included:

Beersheba(C) (or Sheba),[a] Moladah,(D) Hazar Shual,(E) Balah, Ezem,(F) Eltolad,(G) Bethul, Hormah,(H) Ziklag,(I) Beth Markaboth, Hazar Susah, Beth Lebaoth and Sharuhen—thirteen towns and their villages;

Ain, Rimmon,(J) Ether and Ashan(K)—four towns and their villages— and all the villages around these towns as far as Baalath Beer (Ramah in the Negev).(L)

This was the inheritance of the tribe of the Simeonites, according to its clans. The inheritance of the Simeonites was taken from the share of Judah,(M) because Judah’s portion was more than they needed. So the Simeonites received their inheritance within the territory of Judah.(N)

Allotment for Zebulun

10 The third lot came up for Zebulun(O) according to its clans:

The boundary of their inheritance went as far as Sarid.(P) 11 Going west it ran to Maralah, touched Dabbesheth, and extended to the ravine near Jokneam.(Q) 12 It turned east from Sarid(R) toward the sunrise to the territory of Kisloth Tabor and went on to Daberath(S) and up to Japhia. 13 Then it continued eastward to Gath Hepher(T) and Eth Kazin; it came out at Rimmon(U) and turned toward Neah. 14 There the boundary went around on the north to Hannathon and ended at the Valley of Iphtah El.(V) 15 Included were Kattath, Nahalal,(W) Shimron,(X) Idalah and Bethlehem.(Y) There were twelve towns and their villages.

16 These towns and their villages were the inheritance of Zebulun,(Z) according to its clans.(AA)

Allotment for Issachar

17 The fourth lot came out for Issachar(AB) according to its clans. 18 Their territory included:

Jezreel,(AC) Kesulloth, Shunem,(AD) 19 Hapharaim, Shion, Anaharath, 20 Rabbith, Kishion,(AE) Ebez, 21 Remeth, En Gannim,(AF) En Haddah and Beth Pazzez. 22 The boundary touched Tabor,(AG) Shahazumah and Beth Shemesh,(AH) and ended at the Jordan. There were sixteen towns and their villages.

23 These towns and their villages were the inheritance of the tribe of Issachar,(AI) according to its clans.(AJ)

Allotment for Asher

24 The fifth lot came out for the tribe of Asher(AK) according to its clans. 25 Their territory included:

Helkath, Hali, Beten, Akshaph,(AL) 26 Allammelek, Amad and Mishal.(AM) On the west the boundary touched Carmel(AN) and Shihor Libnath. 27 It then turned east toward Beth Dagon,(AO) touched Zebulun(AP) and the Valley of Iphtah El,(AQ) and went north to Beth Emek and Neiel, passing Kabul(AR) on the left. 28 It went to Abdon,[b](AS) Rehob,(AT) Hammon(AU) and Kanah,(AV) as far as Greater Sidon.(AW) 29 The boundary then turned back toward Ramah(AX) and went to the fortified city of Tyre,(AY) turned toward Hosah and came out at the Mediterranean Sea(AZ) in the region of Akzib,(BA) 30 Ummah, Aphek(BB) and Rehob.(BC) There were twenty-two towns and their villages.

31 These towns and their villages were the inheritance of the tribe of Asher,(BD) according to its clans.

Allotment for Naphtali

32 The sixth lot came out for Naphtali according to its clans:

33 Their boundary went from Heleph and the large tree in Zaanannim,(BE) passing Adami Nekeb and Jabneel(BF) to Lakkum and ending at the Jordan. 34 The boundary ran west through Aznoth Tabor and came out at Hukkok.(BG) It touched Zebulun(BH) on the south, Asher on the west and the Jordan[c] on the east. 35 The fortified towns were Ziddim, Zer, Hammath,(BI) Rakkath, Kinnereth,(BJ) 36 Adamah, Ramah,(BK) Hazor,(BL) 37 Kedesh,(BM) Edrei,(BN) En Hazor, 38 Iron, Migdal El, Horem, Beth Anath(BO) and Beth Shemesh.(BP) There were nineteen towns and their villages.

39 These towns and their villages were the inheritance of the tribe of Naphtali, according to its clans.(BQ)

Allotment for Dan

40 The seventh lot came out for the tribe of Dan according to its clans. 41 The territory of their inheritance included:

Zorah, Eshtaol,(BR) Ir Shemesh, 42 Shaalabbin, Aijalon,(BS) Ithlah, 43 Elon, Timnah,(BT) Ekron,(BU) 44 Eltekeh, Gibbethon,(BV) Baalath,(BW) 45 Jehud, Bene Berak, Gath Rimmon,(BX) 46 Me Jarkon and Rakkon, with the area facing Joppa.(BY)

47 (When the territory of the Danites was lost to them,(BZ) they went up and attacked Leshem(CA), took it, put it to the sword and occupied it. They settled in Leshem and named(CB) it Dan after their ancestor.)(CC)

48 These towns and their villages were the inheritance of the tribe of Dan,(CD) according to its clans.

Allotment for Joshua

49 When they had finished dividing the land into its allotted portions, the Israelites gave Joshua son of Nun an inheritance among them, 50 as the Lord had commanded. They gave him the town he asked for—Timnath Serah[d](CE) in the hill country of Ephraim. And he built up the town and settled there.

51 These are the territories that Eleazar the priest, Joshua son of Nun and the heads of the tribal clans of Israel assigned by lot at Shiloh in the presence of the Lord at the entrance to the tent of meeting. And so they finished dividing(CF) the land.(CG)

Footnotes

  1. Joshua 19:2 Or Beersheba, Sheba; 1 Chron. 4:28 does not have Sheba.
  2. Joshua 19:28 Some Hebrew manuscripts (see also 21:30); most Hebrew manuscripts Ebron
  3. Joshua 19:34 Septuagint; Hebrew west, and Judah, the Jordan,
  4. Joshua 19:50 Also known as Timnath Heres (see Judges 2:9)