Font Size
Lefitiku 19:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 19:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)“Bá gbogbo àpéjọpọ̀ àwọn ọmọ Israẹli sọ̀rọ̀, sì wí fún wọn pé: ‘Ẹ jẹ́ mímọ́ nítorí Èmi Olúwa Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.
Read full chapter
Lefitiku 20:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 20:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)“ ‘Torí náà ẹ ya ara yín sí mímọ́ kí ẹ sì jẹ́ mímọ́, torí pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.
Read full chapter
Lefitiku 20:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 20:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
26 (A)Ẹ gbọdọ̀ jẹ́ mímọ́ fún mi torí pé èmi Olúwa fẹ́ mímọ́. Mó sì ti yà yín kúrò nínú àwọn orílẹ̀-èdè yòókù kí ẹ le jẹ́ tèmi.
Read full chapter
1 Peteru 1:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Peteru 1:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
16 (A)Nítorí a ti kọ ọ pé, “Ẹ jẹ́ mímọ́: nítorí tí Èmi jẹ mímọ́!”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.