Add parallel Print Page Options

(A)Ọlọ́run kì yóò ha sì gbẹ̀san àwọn àyànfẹ́ rẹ̀, tí ń fi ọ̀sán àti òru kígbe pè é, tí ó sì mú sùúrù fún wọn?

Read full chapter

Ẹni tí ó dá mi láre wà nítòsí.
    Ta ni ẹni náà tí yóò fẹ̀sùn kàn mí?
Jẹ́ kí a kojú ara wa!
    Ta ni olùfisùn mi?
    Jẹ́ kí ó kò mí lójú!
Olúwa Olódùmarè ni ó ń ràn mí lọ́wọ́.
    Ta ni ẹni náà tí yóò dá mi lẹ́bi?
Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ;
    kòkòrò ni yóò sì jẹ wọn run.

Read full chapter