Add parallel Print Page Options

Ohun mímọ́ àti ohun àìmọ́

15 (A)Nígbà náà ní àwọn Farisi àti àwọn olùkọ́ òfin tọ Jesu wá láti Jerusalẹmu,

Read full chapter

That Which Defiles(A)

15 Then some Pharisees and teachers of the law came to Jesus from Jerusalem and asked,

Read full chapter

30 (A)Lọ́gán, Jesu sì mọ̀ nínú ara rẹ̀ pé agbára jáde lára òun. Ó yípadà láàrín ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó sì béèrè, “Ta ni ó fi ọwọ́ kan aṣọ mi?”

Read full chapter

30 At once Jesus realized that power(A) had gone out from him. He turned around in the crowd and asked, “Who touched my clothes?”

Read full chapter

19 (A)Gbogbo ìjọ ènìyàn sì ń fẹ́ láti fọwọ́ kàn án, nítorí tí àṣẹ ń jáde lára rẹ̀, ó sì mú gbogbo wọn láradá.

Read full chapter

19 and the people all tried to touch him,(A) because power was coming from him and healing them all.(B)

Read full chapter