Add parallel Print Page Options

18 (A)Nígbà náà ni Jesu wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Gbogbo agbára ni ọ̀run àti ní ayé ni a ti fi fún mi.

Read full chapter

18 Then Jesus came to them and said, “All authority in heaven and on earth has been given to me.(A)

Read full chapter

35 Baba fẹ́ Ọmọ, ó sì ti fi ohun gbogbo lé e lọ́wọ́

Read full chapter

35 The Father loves the Son and has placed everything in his hands.(A)

Read full chapter

Tí Jesu sì ti mọ̀ pé Baba ti fi ohun gbogbo lé òun lọ́wọ́, àti pé lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni òun ti wá, òun sì ń lọ sọ́dọ̀ Ọlọ́run;

Read full chapter

Jesus knew that the Father had put all things under his power,(A) and that he had come from God(B) and was returning to God;

Read full chapter

15 (A)Gẹ́gẹ́ bí Baba ti mọ̀ mí, tí èmi sì mọ Baba; mo sì fi ọkàn mi lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.

Read full chapter

15 just as the Father knows me and I know the Father(A)—and I lay down my life for the sheep.(B)

Read full chapter

25 “Baba olódodo, ayé kò mọ̀ ọ́n; ṣùgbọ́n èmi mọ̀ ọ́n, àwọn wọ̀nyí sì mọ̀ pé ìwọ ni ó rán mi.

Read full chapter

25 “Righteous Father, though the world does not know you,(A) I know you, and they know that you have sent me.(B)

Read full chapter