Add parallel Print Page Options

(A)“Alábùkún fún ni àwọn òtòṣì ní ẹ̀mí,
    nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run.
(B)Alábùkún fún ni àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀,
    nítorí a ó tù wọ́n nínú.
(C)Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn tútù,
    nítorí wọn yóò jogún ayé.
(D)Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa
    tí òǹgbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó.
Alábùkún fún ni àwọn aláàánú,
    nítorí wọn yóò rí àánú gbà.
(E)Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́,
    nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run.
Alábùkún fún ni àwọn onílàjà,
    nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n.
10 (F)Alábùkún fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí,
    nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo
    nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.

11 “Alábùkún fún ni ẹ̀yin nígbà tí àwọn ènìyàn bá fi àbùkù kàn yín tí wọn bá ṣe inúnibíni sí yín, tiwọn fi ètè èké sọ̀rọ̀ búburú gbogbo sí yín nítorí mi. 12 (G)Ẹ yọ̀, kí ẹ̀yin sì fò fún ayọ̀, nítorí ńlá ni èrè yín ní ọ̀run, nítorí bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ṣe inúnibíni sí àwọn wòlíì tí ń bẹ ṣáájú yín.

Read full chapter

“Blessed are the poor in spirit,
    for theirs is the kingdom of heaven.(A)
Blessed are those who mourn,
    for they will be comforted.(B)
Blessed are the meek,
    for they will inherit the earth.(C)
Blessed are those who hunger and thirst for righteousness,
    for they will be filled.(D)
Blessed are the merciful,
    for they will be shown mercy.(E)
Blessed are the pure in heart,(F)
    for they will see God.(G)
Blessed are the peacemakers,(H)
    for they will be called children of God.(I)
10 Blessed are those who are persecuted because of righteousness,(J)
    for theirs is the kingdom of heaven.(K)

11 “Blessed are you when people insult you,(L) persecute you and falsely say all kinds of evil against you because of me.(M) 12 Rejoice and be glad,(N) because great is your reward in heaven, for in the same way they persecuted the prophets who were before you.(O)

Read full chapter