Add parallel Print Page Options

(A)Ó tẹríba ó sì dùbúlẹ̀ bí kìnnìún,
    bí abo kìnnìún: ta ni ó gbọdọ̀ jí wọn?

“Ìbùkún ni fún ẹni tí ó bùkún fún ọ,
    kí ìfibú jẹ́ ti ẹni tí ó fi ọ́ bú!”

Read full chapter

(A)Ọ̀kan nínú àwọn àgbà náà sì wí fún mi pé, “Má ṣe sọkún: kíyèsi i, kìnnìún ẹ̀yà Juda, Gbòǹgbò Dafidi, tí borí láti ṣí ìwé náà, àti láti tú èdìdì rẹ̀ méjèèje.”

Read full chapter