Add parallel Print Page Options

49 (A)Títí láéláé, èmi yóò máa yìn ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ Olúwa;
    Èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ.

Read full chapter

50 (A)Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, Olúwa,
    láàrín àwọn àjèjì orílẹ̀-èdè: èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ.

Read full chapter