Add parallel Print Page Options

Ìdájọ́ àti ìgbàlà

65 (A)“Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;
    Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi.
Sí àwọn orílẹ̀-èdè tí kò pe orúkọ mi,
    Ni èmi wí pé, ‘Èmi nìyìí, Èmi nìyìí.’

Read full chapter

30 (A)Ǹjẹ́ kí ni àwa ó ha wí? Pé àwọn Kèfèrí, tí kò lépa òdodo, ọwọ́ wọn tẹ òdodo, ṣùgbọ́n òdodo tí ó ti inú ìgbàlà wá ni.

Read full chapter