Add parallel Print Page Options

20 (A)Ṣùgbọ́n Isaiah tilẹ̀ láyà, ó wí pé,

“Àwọn tí kò wá mi rí mi;
    Àwọn tí kò béèrè mi ni a fi mí hàn fún.”

21 (B)Ṣùgbọ́n nípa ti Israẹli ni ó wí pé,

“Ní gbogbo ọjọ́ ni mo na ọwọ́ mi
    sí àwọn aláìgbọ́ràn àti aláríwísí ènìyàn.”

Read full chapter