Add parallel Print Page Options

25 Má ṣe jáde lọ sí orí pápá
    tàbí kí o máa rìn ní àwọn
ojú ọ̀nà, nítorí ọ̀tá náà ní idà,
    ìpayà sì wà níbi gbogbo.

Read full chapter

(A)Ní ọjọ́ kejì tí Paṣuri tú u sílẹ̀ nínú túbú, Jeremiah sì sọ fún un wí pé, “orúkọ Olúwa fun ọ kì í ṣe Paṣuri bí kò ṣe ìpayà.

Read full chapter

10 Mo gbọ́ sísọ ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́,
    ìbẹ̀rù ni ibi gbogbo
Fi í sùn! Jẹ́ kí a fi sùn!
    Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ mi ń dúró
kí èmi ṣubú, wọ́n sì ń sọ pé,
    Bóyá yóò jẹ́ di títàn,
nígbà náà ni àwa yóò borí rẹ̀,
    àwa yóò sì gba ẹ̀san wa lára rẹ̀.”

Read full chapter

(A)Kí ni nǹkan tí mo tún rí?
    Wọ́n bẹ̀rù,
wọ́n sì ń padà sẹ́yìn,
    wọ́n ti ṣẹ́gun àwọn jagunjagun.
Wọ́n sá,
    wọn kò sì bojú wẹ̀yìn,
ìbẹ̀rù sì wà níbi gbogbo,”
    ni Olúwa wí.

Read full chapter

29 (A)Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn ni wọn ó kó lọ;
    àgọ́ wọn yóò di ìṣínípò padà
pẹ̀lú gbogbo ẹrù àti ìbákasẹ wọn.
    Àwọn ènìyàn yóò ké sórí wọ́n pé;
    ‘Ẹ̀rù yí káàkiri!’

Read full chapter