Add parallel Print Page Options

25 Má ṣe jáde lọ sí orí pápá
    tàbí kí o máa rìn ní àwọn
ojú ọ̀nà, nítorí ọ̀tá náà ní idà,
    ìpayà sì wà níbi gbogbo.

Read full chapter

(A)Kí ni nǹkan tí mo tún rí?
    Wọ́n bẹ̀rù,
wọ́n sì ń padà sẹ́yìn,
    wọ́n ti ṣẹ́gun àwọn jagunjagun.
Wọ́n sá,
    wọn kò sì bojú wẹ̀yìn,
ìbẹ̀rù sì wà níbi gbogbo,”
    ni Olúwa wí.

Read full chapter

29 (A)Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn ni wọn ó kó lọ;
    àgọ́ wọn yóò di ìṣínípò padà
pẹ̀lú gbogbo ẹrù àti ìbákasẹ wọn.
    Àwọn ènìyàn yóò ké sórí wọ́n pé;
    ‘Ẹ̀rù yí káàkiri!’

Read full chapter

13 (A)Nítorí mo gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpayà tí ó yí mi ká;
    tí wọn gbìmọ̀ pọ̀ sí mi,
wọ́n sì ṣọ̀tẹ̀ sí mi
    láti gba ẹ̀mí mi.

Read full chapter